Prayer Wall Requests
personal
Jehovah Adonai El Shaddai Elohim Yahweh e gba eto mi fun mi ni ibi ise mi. Gbogbo owo tio ye ki won fun mi ati ipo to ye ki nwa Oluwa gba fun mi loruko Jesu, Ki ogo yin farahan lori mi ati ise mi nipa agbara Olorun Jehovah Adonai Read more…